Ariwo Ògún Ye! Ogun in Trinidad and Tobago 

editoreditorCulturePoetry1 week ago91 Views

Ògún, the wealthy husband of my mother,
The mighty deity who moves with great power,
The one who bathes in blood at home,
The one who adorns himself with sacred garments.
Ògún, the owner of two swords,
One for clearing the bush, the other for blocking the path.
On Ògún’s day, he descends from heaven to earth,
Clothed in a robe of fire,
And a garment of blood around his neck.
Ògún, the owner of wealth, the path to prosperity,
Ògún, the owner of the mighty iron from the realm of the heavens.

My Ògún is seven in one:
Ògún, the fierce warrior, is renowned,
Ògún, the prosperous one, is trusted,
Ògún, the cultivator, nurtures the yam,
Ògún, the roadbuilder, paves the way,
Ògún, the hairy one, watches over the ram,
Ògún, the pathfinder, feasts on the snail,
Ògún, the mighty one, stands firm behind the fortress.

Ògún onírè ọkọ ò mi Irúnmolè tí ń rù mìnìmìnì Òlómi nílé fèjè wè Òlása nílé fìmọ̀bímọ̀ bora Ògún aládàá méjì Ó fìkán sánko, ó fìkán yènà Ojó Ògún ń fìkòlé òrun bò wá s’ílé ayé Asa iná ló mú bora èwù èjè ló wọ̀ sọ́rùn o Ògún onílé owó ọlọ́nà ọla Ògún onílé kángun kàngun òde òrun Méje l’Ògún mi Ògún alárá nií gbajá Ògún onírè a gbàgbò Ògún ìkọlà a gbà ‘gbín Ògún elémoná nií gbèsun asu Ògún akirun á gbà wo àgbò Ògún gbénàgbénà eran ahun níí je Ògún mákinde ti d’Ògún léhìn odi Bí ò bá gba tápà á gbàbókí á gba húnkùnhúnkùn á gba tèmbèrí o jàre mo ní e má bógúnrún fìjà seré Ògún òlódodo l’Ògún tèmi Ọmọ Orórínà, ọmọ Tàbúfú Morú nítorípé l’ójó Ògún kó délé ayé, Emu ló kó bèrè o ḿgbà tó délè ìrè o Ògún onílé owó, Olónà olà Ògún ónile, kángunkàgun òde òrun Mo ní e má aàbógùn fìjà sére o o Ara Ògún kan gó gó gó

If he does not take the cutlass, he takes the hoe,
He takes the hammer, he takes the chisel,
He takes the digging tool, oh please!
I say, do not provoke Ògún into a playful fight.
Ògún, the truthful one, is my Ògún,
The child of Orórínà, the child of Tàbúfú.

I am fierce because on the day Ògún came to earth,
He brought palm wine to begin his journey to the land of prosperity.
Ògún, the owner of wealth, the path to prosperity,
Ògún, the owner of the mighty iron from the realm of the heavens.
I say, do not provoke Ògún into a playful fight.
The body of Ògún stands firm, strong, and unshakable.

 Mayowa Adeyemo praises Ogun (God of Iron)

Leave a reply

Loading Next Post...
Sign In Sidebar Search Trending 0 Cart
Loading

Signing-in 3 seconds...

Cart
Cart updating

ShopYour cart is currently is empty. You could visit our shop and start shopping.